Bi sekere ba ti dun oo Konga a te le A te le Ijo ma tele Antrans ko gi le o fun mi jaree Lateko de challengi A gba guru mara ji Awole pelu Bugati Ankara lori Fasasi Idi n be ni Ibadan o Oke be ni Ibadan o Idi Arere Idi Ayunre Oke Sango Oke Mo Po Ema je ko di ja Olosho yapa ni Bodija o Pelu sokoto pe n pe Awon omo mi ni Molete Ema soko fun eye Twitter Alomo metta feya speaker Furo rabata fe ya bumber Them say them to buggi down Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo E shoutout si awon omo Uni Leed city de Ibadan Poly Ebami ki Kunle Silencer Omo Musulumi to fa poli Ero to lo London Ebami ki Kayode Kida Tiringbeku teletele Omo ibadan to di nigga Omo woli to n fa taba Basira su sara ko ta ba Omugo fe high ogun lada Won de ni momo re feya fada Qdot fe silekun fe kun O yo tan owa be kun bekun I turn up tan osi seku Ka to fi embivadale le odi seven Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ni le Oluyole ooo Awon omo Lagelu Ujo sokky mo gbe wa o No be skelewu Atana wole pelu sanpeni Ki ni a de temi complaini Pe owo afefe la fi sustaini Ahhen ti Naira ba ti tan Mabinu ma ko Pounsi jade Ko fun mi lolosho to wo gown Won fun mi lorogbo to ti brown Eyi ko lemaso fun wa Pe Oshogbo ti di town Eeeeen we rocking Gucci Gucci Ajoko sori chair kusin Eran chikin la gbe ah nu jawee Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ikorodu ni oga wa nana nana nana nana Kunle Oluyole omo a fi akara fo eko mo nana nana nana Shakoye Bami Osa Malik mama high flyer ni lbadan Aleshi mama Abiodun Olayinka Mili bo lo nu Mr Ayodele Momodu Olojede Olamide Baddo Antrans ni ori beat afo Up face on the beat ti babo