O òré mi láídé Níbo ló dà l'ójó Saturday yìí Hmmm wón se party níhìn o L'ókè súnáà léhìn kùlé àwon làtí Ànkárá la dá Kòstúmù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Ànkárá la dá Kòstúmù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Oh we're happy people And that's who we are We're having fun We're the children of the Sun Oh we're happy people And that's who we are We don't care We're the children of the Sun O òré mi laide Níbo ló kàn l'ójó Sunday yìí Hmmm wón gbéyàwó níhin o L'ókè pópó légbe ilé àwon toyeeb Ànkárá la dá Kòstúmù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Ànkárá la dá Gèlè búlúù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Oh we're happy people And that's who we are We're having fun We are the children of the Sun Oh oh we happy people And that's who we are We don't care We are the children of the Sun Oh oh we happy people And that's who we are We're having fun We are the children of the Sun Oh oh we happy people And that's who we are Oh we don't care We are the children of the Sun Oh oh we happy people And that's who we are now Oh we don't care We are the children of the Sun